Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 23:39 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Torí náà, bẹ̀rẹ̀ láti ọjọ́ kẹẹ̀dógún osù kéje lẹ́yìn ìgbà tí ẹ ti kórè ilẹ̀ náà, ẹ se àjọ̀dún yìí fún Olúwa ní ọjọ́ méje. Ọjọ́ kìn-ín-ní jẹ́ ọjọ́ ìsinmi, ọjọ́ kẹjọ pẹ̀lú si tún jẹ́ ọjọ́ ìsinmi.

Ka pipe ipin Léfítíkù 23

Wo Léfítíkù 23:39 ni o tọ