Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 23:37 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

(“ ‘Ìwònyí ni àwon àjọ̀dún tí Olúwa ti yàn tí ẹ gbọdọ̀ kéde gẹ́gẹ́ bí i ìpàdé mímọ́ fún mímu àwọn ọrẹ tí a fi iná ṣe sí Olúwa wá—ọrẹ sísun àti ọrẹ ọkà, ọrẹ ẹbọ àti ọrẹ ohun mímu, fún ọjọ́ kọ̀ọ̀kan:

Ka pipe ipin Léfítíkù 23

Wo Léfítíkù 23:37 ni o tọ