Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 22:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tàbí bí ó bá fọwọ́ kan èyíkéyìí nínú ohun tí ń rákò, tí ó sọ ọ́ di aláìmọ́, tàbí ẹnikẹ́ni tí ó sọ ọ́ di àìmọ́, ohunkóhun yówù kí àìmọ́ náà jẹ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:5 ni o tọ