Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 22:31-33 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

31. “Ẹ pa òfin mi mọ́, kí ẹ sì máa ṣe wọ́n. Èmi ni Olúwa.

32. Ẹ má ṣe ba orúkọ mímọ́ mi jẹ́. Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gbọdọ̀ mọ̀ mí ní mímọ́. Èmi ni Olúwa tí ó sọ yín di mímọ́.

33. Tí ó sì mú yín jáde láti Éjíbítì wá láti jẹ́ Ọlọ́run yín. Èmi ni Olúwa.”

Ka pipe ipin Léfítíkù 22