Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 22:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kò gbọdọ̀ gba irú ẹranko bẹ́ẹ̀ lọ́wọ́ àlejò kankan láti fi rúbọ gẹ́gẹ́ bí oúnjẹ sí Ọlọ́run yín. A kò ní gbà wọ́n fún yín nítorí pé wọ́n ní àbùkù wọ́n sì díbàjẹ́.’ ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 22

Wo Léfítíkù 22:25 ni o tọ