Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 21:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kò gbọdọ̀ sí iran àlùfáà tí ó jẹ́ alábùkù ara tí ó gbọdọ̀ wá fi iná sun ẹbọ sí Ọlọ́run. Nítorí pé ó jẹ́ alábùkù, kò gbọdọ̀ sún mọ́ tòsí láti gbé ẹbọ wá fún Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 21

Wo Léfítíkù 21:21 ni o tọ