Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 2:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ fi iyọ̀ dun gbogbo ọrẹ ohun jíjẹ yín. Ẹ má se aláì fi iyọ̀ májẹ̀mu Ọlọ́run yín sínú àwọn ọrẹ ohun jíjẹ yín, ẹ fi iyọ̀ sí gbogbo ọrẹ yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:13 ni o tọ