Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Gbogbo ọrẹ ohun jíjẹ tí ẹ bá mú wá fún Olúwa kò gbọdọ̀ ní ìwúkàrà nínú, nítorí pé ẹ kò gbọdọ̀ sun ohun wíwú tàbí oyin nínú ọrẹ tí ẹ fi iná sun sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 2

Wo Léfítíkù 2:11 ni o tọ