Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 19:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Má a pa àṣẹ mi mọ́.“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ jẹ́ kí ohun ọ̀sìn rẹ máa gùn pẹ̀lú ẹ̀yà mìíràn.“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ gbin dàrúdàpọ̀ oríṣìí irúgbìn méjì sínú oko kan.“ ‘Ìwọ kò gbọdọ̀ wọ aṣọ èyí tí a fi oríṣìí ohun èlò ìhunṣọ méjì ṣe.

Ka pipe ipin Léfítíkù 19

Wo Léfítíkù 19:19 ni o tọ