Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 17:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí rí bẹ́ẹ̀ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì le è máa mú ẹbọ wọn tí wọn ti rú ní ìta gbangba wá sí iwájú Olúwa: wọ́n gbọdọ̀ mú un wá ṣíwájú àlùfáà àní sí Olúwa ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé: kí wọ́n sì rú wọn gẹ́gẹ́ bí ẹbọ àlàáfíà sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 17

Wo Léfítíkù 17:5 ni o tọ