Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 17:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Torí pé ẹ̀mí gbogbo ẹ̀dá ni ẹ̀jẹ̀ rẹ̀, torí náà ni mo fi kìlọ̀ fún àwọn ọmọ Ísírẹ́lì pé wọn kò gbọdọ̀ jẹ ẹ̀jẹ̀ ohun abẹ̀mí kankan: torí pé nínú ẹ̀jẹ̀ ohun abẹ̀mí wọ̀nyí ni ẹ̀mí wọn wà: ẹnikẹ́ni tí ó bá jẹ ẹ́ ni a ó gé kúrò.

Ka pipe ipin Léfítíkù 17

Wo Léfítíkù 17:14 ni o tọ