Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 16:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọjọ́ yìí yóò jẹ́ ọjọ́ ìsinmi pátapáta fún un yín: ẹ̀yin yóò sì ṣẹ́ ara yín: Èyí yóò sì jẹ́ ìlànà títí láé.

Ka pipe ipin Léfítíkù 16

Wo Léfítíkù 16:31 ni o tọ