Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 16:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni yóò jẹ́ ìlànà títí láé fún yín: pé ní ọjọ́ kẹwàá oṣù keje ni ẹ gbọdọ̀ ṣẹ́ ara yín: kí ẹ má ṣe ṣe iṣẹ́ kankan, yálà onílé tàbí àlejò tí ó ń gbé pẹ̀lú yín.

Ka pipe ipin Léfítíkù 16

Wo Léfítíkù 16:29 ni o tọ