Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 16:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni yóò ṣe ètùtù fún ibi mímọ́ jùlọ nítorí àìmọ́ àwọn ará Ísírẹ́lì àti nítorí gbogbo ìrékọjá wọn àti ìṣọ̀tẹ̀ wọn nípa ẹ̀ṣẹ̀ wọn gbogbo, bákan náà ni yóò sì ṣe fún àgọ́ ìpàdé, èyi tí ó wà láàrin wọn nínú àìmọ́ wọn.

Ka pipe ipin Léfítíkù 16

Wo Léfítíkù 16:16 ni o tọ