Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 16:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Yóò sì mú àwo tùràrí tí ó kún fún èédú tí a ti sun pẹ̀lú iná láti orí pẹpẹ wá ṣíwájú Olúwa: àti ẹ̀kúnwọ́ méjì tùràrí tí a gún kúnná yóò sì mú un wá sí ẹ̀yìn aṣọ títa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 16

Wo Léfítíkù 16:12 ni o tọ