Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 15:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọjọ́ kẹjọ kí ó mú àdàbà méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì, kí ó sì wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé níwájú Olúwa, kí ó sì kó wọn fún àlùfáà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 15

Wo Léfítíkù 15:14 ni o tọ