Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 14:56-57 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

56. fún ìwú, fún èélá àti ibi ara dídán.

57. Láti mú kí a mọ̀ bóyá nǹkan mọ́ tàbí kò mọ́.Ìwọ̀nyí ni àwọn òfin fún àrùn àwọ̀ ara tí ó ń ràn ká àti ẹ̀tẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14