Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 14:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àlùfáà pàṣẹ pé kí wọn pa ọ̀kan nínú àwọn ẹyẹ náà sórí omi tí ó mọ́ tó wà nínú ìkòkò amọ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:5 ni o tọ