Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 14:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òfin nìyí fún ẹnikẹ́ni tí ó bá ní àrùn ara tí ó le ran tí kò sì lágbára láti rú ẹbọ tí ó yẹ fún ìwẹ̀nùmọ́ bí a ti fi lélẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 14

Wo Léfítíkù 14:32 ni o tọ