Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:56 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àlùfáà bá yẹ̀ ẹ́ wò ti ẹ̀tẹ̀ náà bá ti kúrò níbẹ̀: lẹ́yìn tí a ti fọ̀ ohunkóhun tí ó mú, kí ó ya ibi tí ó bàjẹ́ kúrò lára aṣọ náà, awọ náà, aṣọ híhun náà tàbí aṣọ tìta náà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:56 ni o tọ