Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:52 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó gbọdọ̀ sun aṣọ náà tàbí irun àgùtàn náà, aṣọ híhun náà tàbí awọ náà ti ó ni ìbàjẹ́ kan lára rẹ̀ ni iná torí pé ẹ̀tẹ̀ tí í pa ni run ni. Gbogbo nǹkan náà ni ẹ gbọdọ̀ sun ní iná.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:52 ni o tọ