Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:45 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí ẹni tí àrùn náà wà ní ara rẹ̀ wọ àkísà. Kí ó má ṣe gé irun rẹ̀, kí ó daṣọ bo ìṣàlẹ̀ ojú rẹ̀ kí ó sì máa ké wí pé, ‘Aláìmọ́! Aláìmọ́!’

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:45 ni o tọ