Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àlùfáà yẹ làpálàpá náà wò, ní ọjọ́ kéje bí kò bá ràn ká gbogbo àwọ̀ ara: tí kò sì jinlẹ̀ ju inú àwọ̀ ara lọ. Kí àlùfáà pè é ní mímọ́: Kí ó fọ aṣọ rẹ̀: òun yóò sì mọ́.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:34 ni o tọ