Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n bí àlùfáà bá yẹ egbò yìí wò tí kò sì jinlẹ̀ ju àwọ̀ ara lọ tí kò sì sí irun dúdú kan níbẹ̀. Kí àlùfáà fi ẹni náà pamọ́ fún ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:31 ni o tọ