Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àlùfáà yẹ ẹni náà wò ní ọjọ́ keje, bí ó bá ń ràn ká àwọ̀ ara, kí àlùfáà kí ó pè é ní aláìmọ́. Àrùn ara tí ń ràn ni èyí.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:27 ni o tọ