Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí àlùfáà yẹ̀ ẹ́ wò, bí ó bá jinlẹ̀ jù awọ ara rẹ̀ lọ tí irun tirẹ̀ sì ti di funfun: kí àlùfáà pe ẹni náà ni aláìmọ́. Àrùn ara tí ó le ràn ló yọ padà lójú oówo náà.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:20 ni o tọ