Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àlùfáà bá ti rí ẹran ara rẹ̀ kan kí ó pè é ni aláìmọ́. Ẹran ara rẹ̀ di àìmọ́ torí pé ó ní àrùn tí ń ràn.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:15 ni o tọ