Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àrùn ara burúkú gbáà ni èyí, kí àlùfáà jẹ́ kí ó di mímọ̀ pé irú ẹni bẹ́ẹ̀ kò mọ́: kí ó má ṣe ya ẹni náà sọ́tọ̀ fún àyẹ̀wò torí pé aláìmọ́ ni ẹni náà jẹ́ tẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 13

Wo Léfítíkù 13:11 ni o tọ