Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ má ṣe kúrò ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé, bí ẹ bá kúrò níbẹ̀, ẹ ó kùú, nítorí pé òróró ìtasórí Olúwa wà lórí yín” Wọ́n sì ṣe bí Mósè ti wí.

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:7 ni o tọ