Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Árónì sì dá Mósè lóhùn pé, “Lónìí tí wọ́n rú ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ àti ẹbọ sísun wọn níwájú Olúwa ni irú èyí tún sẹlẹ̀ sí mi. Ǹjẹ́ inú Olúwa yóò wá dùn bí mo bá jẹ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ lónìí?”

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:19 ni o tọ