Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí Mósè wádìí nípa ewúrẹ́ ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀ tó sì rí i pé wọ́n ti sun ún, ó bínú sí Élíásárì àti Ítamárì, àwọn ọmọ Árónì yóòkù, ó sì bèèrè pé,

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:16 ni o tọ