Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 10:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nádábù àti Ábíhù tí í ṣe ọmọ Árónì sì mú àwo tùràrí kọ̀ọ̀kan, wọ́n fi iná àti tùràrí sínú rẹ̀, wọ́n sì rú iná àìmọ́ níwájú Olúwa, èyí tó lòdì sí àṣẹ Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 10

Wo Léfítíkù 10:1 ni o tọ