Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 9:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Jósúà pe àwọn ọmọ Gíbíónì jọ pé, “Èé ṣe tí ẹ̀yin fí tàn wá wí pe, ‘Àwa gbé ní ibi tí ó jìnnà sí yín,’ nígbà tí ó jẹ́ pé tòsí wa ní ẹ̀yin ń gbé?

Ka pipe ipin Jóṣúà 9

Wo Jóṣúà 9:22 ni o tọ