Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 9:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Nísinsinyìí, nígbà tí gbogbo ọba tó wà ní ìwọ̀-oòrùn Jọ́dánì gbọ́ nípa nǹkan wọ̀nyí, àwọn náà tí ó wà ní orí òkè àti àwọn tí ó wà ní ẹṣẹ̀ òkè, àti gbogbo àwọn tí ó wà ní agbégbé Òkun ńlá títí ó fi dé Lẹ́bánónì (àwọn ọba Hítì Ámórì, Kénánì, Pérísì Hífì àti Jébúsì)

2. wọ́n sì kó ara wọn jọ láti bá Jósúà àti Ísírẹ́lì jagun.

Ka pipe ipin Jóṣúà 9