Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn Kénánì àti àwọn ènìyàn ìlú tí ó kù náà yóò gbọ́ èyí, wọn yóò sì yí wa ká, wọn yóò sì ké orúkọ wa kúrò ní ayé. Kí ni ìwọ ó ha ṣe fún orúkọ ńlá à rẹ?”

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:9 ni o tọ