Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jósúà sì wí pé, “Háà, Olúwa Ọlọ́run alágbára, nítorí i kiín ni ìwọ ṣe mú àwọn ènìyàn yìí kọjá a Jọ́dánì, láti fi wọ́n lé àwọn ará Ámórì lọ́wọ́; láti pa wọn run? Àwa ìbá mọ̀ kí a dúró ní òdì kéjì Jọ́dánì?

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:7 ni o tọ