Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

wọ́n sì pa àwọn bí mẹ́rìndínlógójì nínú wọn. Wọ́n sì ń lépa àwọn ará Ísírẹ́lì láti ibodè ìlú títí dé Ṣébárímù, wọ́n sì pa àwọn tí ń sọ̀kalẹ̀. Àyà àwọn ènìyàn náà sì já, ọkàn wọn sì pámi.

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:5 ni o tọ