Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, gbogbo àwọn ọkùnrin tó jáde láti Éjíbítì ni a ti kọ ní ilà, síbẹ̀ gbogbo ènìyàn tí a bí nínú asálẹ̀ lẹ́yìn tí wọ́n jáde ní Éjíbítì ni wọn kò kọ ní ilà.