Nígbà náà ni Olúwa wí fún Jóṣúà pé, “Fi akọ òkúta ṣe abẹ kí o sì kọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ní ilà ní ìgbà ẹ̀ẹ̀kéjì.”