Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóṣúà sì to òkúta méjìlá (12) náà sí àárin odò Jọ́dánì fún ìrántí ní ọ̀kánkán ibi tí àwọn àlùfáà tí ó ru àpótí ẹ̀rí dúró sí. Wọ́n sì wà níbẹ̀ di òní yìí.

Ka pipe ipin Jóṣúà 4

Wo Jóṣúà 4:9 ni o tọ