Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 3:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún àwọn àlùfáà tí ó ru àpótí ẹ̀rí náà: ‘Nígbà tí ẹ bá dé etí omi Jọ́dánì, ẹ lọ kí ẹ sì dúró nínú odò náà.’ ”

Ka pipe ipin Jóṣúà 3

Wo Jóṣúà 3:8 ni o tọ