Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

omi tí ń ti òkè sàn wá dúró. Ó sì gbájọ bí òkítì ní òkèèrè, ní ìlú tí a ń pè ní Ádámù, tí ó wà ní tòsí Sárétanì; nígbà tí omi tí ń ṣàn lọ sínú òkun aginjù, (Òkun Iyọ̀) gé kúrò pátapáta. Bẹ́ẹ̀ ni àwọn ènìyàn kọjá sí òdì kejì ní ìdojúkọ Jẹ́ríkò.

Ka pipe ipin Jóṣúà 3

Wo Jóṣúà 3:16 ni o tọ