Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 3:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ni ẹ̀yin yóò fi mọ̀ pé Ọlọ́run alààyè wà ní àárin yín àti pé dájúdájú yóò lé àwọn ará Kénánì, àwọn ará Hítì, Hífì, Pérésì, Gágáṣì, Ámórì àti Jébúsì jáde níwájú u yín.

Ka pipe ipin Jóṣúà 3

Wo Jóṣúà 3:10 ni o tọ