Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 23:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹ bá sẹ̀ sí májẹ̀mu Olúwa Ọlọ́run yín, èyí tí ó pàṣẹ fún un yín, tí ẹ bá sì lọ tí ẹ sì sin àwọn òrìṣà tí ẹ sì tẹ orí ba fún wọn, ìbínú gbígbóná Olúwa yóò wá sórí i yín, ẹ̀yin yóò sì ṣègbé kíákíá kúrò ní ilẹ̀ dáradára tí ó ti fi fún un yín”

Ka pipe ipin Jóṣúà 23

Wo Jóṣúà 23:16 ni o tọ