Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 23:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Nísinsin yìí èmi ti fẹ́ máa lọ sí ibi tí àwọn àgbà ń rè. Ẹ mọ̀ pẹ̀lú gbogbo ọkàn yín àti àyà yín pé, kò sí ohun kan tí ó kùnà nínú àwọn ìlérí rere gbogbo tí Olúwa Ọlọ́run yín fi fún un yín. Gbogbo ìlérí tó ti se kò sí ọ̀kan tí ó kùnà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 23

Wo Jóṣúà 23:14 ni o tọ