Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìn yìí tí Olúwa Ọlọ́run yín ti fún àwọn arákùnrin yín ní ìsinmi gẹ́gẹ́ bí ó ti ṣèlérí, ẹ padà sí ilẹ̀ yín níbi tí Mósè ìránṣẹ́ Olúwa fi fún yin ní òdì kéjì Jọ́dánì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:4 ni o tọ