Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fínéhásì ọmọ Élieásárì, àlùfáà wí fún Réúbẹ́nì, Gádì àti Mánásè, “Ní òní ni àwa mọ̀ pé Olúwa wà pẹ̀lú wa, nítorí tí ẹ̀yin kò hùwà àìṣòtítọ́ sí Olúwa ní orí ọ̀rọ̀ yí nísinsin yìí, ẹ̀yin ti yọ àwọn ará Ísírẹ́ì kúrò ní ọwọ́ Olúwa”.

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:31 ni o tọ