Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ilẹ̀ ìní yín bá di àìmọ́, ẹ wá sí orí ilẹ̀ ìní Olúwa, ní ibi tí àgọ́ Olúwa dúró sí, kí ẹ sì pín ilẹ̀ náà pẹ̀lú wa. Ṣùgbọ́n kí ẹ má ṣe sọ̀tẹ̀ sí Olúwa tàbí sí wa nípa mímọ pẹpẹ fún ara yín, lẹ́yìn pẹpẹ Olúwa Ọlọ́run wa.

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:19 ni o tọ