Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 21:44 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa sì fún wọn ní ìsinmi ní gbogbo ọ̀nà, gẹ́gẹ́ bí ó ti sèlèrí fún baba ńlá wọn. Kò sì sí ọ̀kankan nínú àwọn ọ̀ta wọn tí ó lè dojú kọ wọ́n. Olúwa sì fi gbogbo àwọn ọ̀ta wọn lé wọn ní ọwọ́.

Ka pipe ipin Jóṣúà 21

Wo Jóṣúà 21:44 ni o tọ