Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 2:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni àwọn ọkùnrin méjì náà padà. Wọ́n sì ṣọ̀kalẹ̀ láti orí òkè, wọ odò, wọ́n sì wá sí ọ̀dọ̀ Jóṣúà ọmọ Núnì; wọ́n sì sọ fún un gbogbo ohun tí ó ti sẹlẹ̀ sí wọn.

Ka pipe ipin Jóṣúà 2

Wo Jóṣúà 2:23 ni o tọ